Gálátíà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ẹni tí ó bá ń fúnrúngbìn sípa ti ara yóò ká ìdíbàjẹ́ ti ara ṣùgbọ́n ẹni tí ń fúnrúngbìn sípa ti ẹ̀mí yóò ti inú ẹ̀mí ká ìyè àìnípẹ̀kun.

Gálátíà 6

Gálátíà 6:1-13