Gálátíà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a má ṣe tàn yín jẹ; a kò lè gan Ọlọ́run: nítorí ohunkóhun tí ènìyàn bá fúnrúgbìn, òhun ni yóò sì ká.

Gálátíà 6

Gálátíà 6:4-17