Gálátíà 3:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá sì jẹ́ ti Kírísítì, ǹjẹ́ ẹ̀yin ní irú-ọmọ Ábúráhámù, àti àrólé gẹ́gẹ́ bí ìlérí.

Gálátíà 3

Gálátíà 3:25-29