Gálátíà 3:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò le sí Júù tàbí Gíríkì, ẹrú tàbí òmìnira, ọkùnrin tàbí ọbìnrin nítorí pé ọ̀kan ni nínú Kírísítì Jésù.

Gálátíà 3

Gálátíà 3:25-29