Ẹ́sítà 8:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Módékáì sì kúrò níwájú ọba, ó wọ aṣọ aláró àti funfun, ó dé adé e wúrà ńlá pẹ̀lú ìgbànú eléṣèé àlùkò dáradára, ìlú Ṣúṣà sì ṣe àjọyọ̀ ńlá.

Ẹ́sítà 8

Ẹ́sítà 8:6-17