Ẹ́sítà 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ìránṣẹ́ ayaba bí àṣà tí wọ́n ń gun ẹṣin ọba, sáré jáde, wọ́n sáré lọ nípa àṣẹ ọba. A sì tún gbé àṣẹ náà jáde ní ilé ìṣọ́ ti Ṣúṣà.

Ẹ́sítà 8

Ẹ́sítà 8:12-17