Báwo ni àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin Síónì tí ó ṣe iyebíye,tí wọ́n wọn iye wúrà ṣewá dàbí ìkòkò amọ̀ lásániṣẹ́ ọwọ́ amọ̀kòkò!