Ẹkún Jeremáyà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni wúrà ṣe sọ ògo dídán rẹ̀ nù,wúrà dídára di àìdán!Òkúta ibi mímọ́ wá túkásí oríta gbogbo òpópó.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:1-5