Ẹkún Jeremáyà 4:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, ojú wa kùnàfún wíwo ìrànlọ́wọ́ asán;láti orí ìṣọ́ wa ni à ń wòfún orílẹ̀-èdè tí kò le gbà wá là.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:13-20