Olúwa ti tú wọn ká fún-ra-ra-rẹ̀;kò sí bojú tó wọn mọ́.Kò sí ọ̀wọ̀ fún olórí àlùfáà mọ́,àti àánú fún àwọn àgbà.