Ẹkún Jeremáyà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn àwọn ènìyànkígbe jáde sí Olúwa.Odi ọmọbìnrin Síónì,jẹ́ kí ẹkún rẹ̀ ṣàn bí odòní ọ̀sán àti òru;má ṣe fi ara rẹ fún ìtura,ojú rẹ fún ìsinmi.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:16-22