Ẹkún Jeremáyà 2:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báwo ni Olúwa ṣe bo ọmọbìnrin Síónìpẹ̀lú ìkúùkù ìbínú rẹ̀!Ó sọ ògo Ísírẹ́lì kalẹ̀Láti ọ̀run sí ayé;kò rántí àpótí-ìtìṣẹ̀ rẹ̀ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.

Ẹkún Jeremáyà 2

Ẹkún Jeremáyà 2:1-7