“Jẹ́ kí ìwà ìkà wọn wá síwájú rẹ;jẹ wọ́n níyàbí o se jẹ mí níyànítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi.Ìrora mi pọ̀ọkàn mi sì káàárẹ̀.”