Ékísódù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn Fáráò sì yigbì, kò sì jẹ́ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ó lọ, bí Olúwa ti sọ láti ẹnu Mósè.

Ékísódù 9

Ékísódù 9:32-35