Ékísódù 9:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Fáráò rí i pé òjò àti yìnyín àti àrá ti ń sán ti dáwọ́ dúró, ó tún ṣè ní ẹ̀ẹ̀kan sí i. Ọkan Fáráò àti àwọn ìjòyè rẹ̀ yigbì.

Ékísódù 9

Ékísódù 9:27-35