Ékísódù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti yẹ kí n ti na ọwọ́ mi jáde láti kọ lù ọ́ àti àwọn ènìyàn rẹ pẹ̀lú ohun búburú ti kò bá ti run yín kúrò ni orí ilẹ̀.

Ékísódù 9

Ékísódù 9:5-20