Ékísódù 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, èmi yóò rán ìdààmú ti ó ní agbára gidigidi sí ọ, sí àwọn ìjòyè rẹ àti sí àwọn ènìyàn rẹ, kí ìwọ kí ó lè mọ̀ pé, kò sí ẹni bí èmi ni gbogbo ayé.

Ékísódù 9

Ékísódù 9:8-24