Ékísódù 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún un pé, ‘Olúwa Ọlọ́run àwọn Hébérù rán mi sí ọ láti sọ fún ọ pé: Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mi kí ó lọ, kí wọn kí ó lè sìn mi ni ihà. Ṣùgbọ́n títí di àkókò yìí, ìwọ kò gba.

Ékísódù 7

Ékísódù 7:9-25