Ékísódù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tọ Fáráò lọ ni òwúrọ̀ kùtùkùtù bí ó ti ń lọ sí etí odò, dúró ni etí bèbè odò Náílì láti pàdé rẹ, mú ọ̀pá rẹ tí ó di ejò ni ọwọ́ rẹ.

Ékísódù 7

Ékísódù 7:5-17