Ékísódù 40:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú òróró ìtasórí, kí ó sì ta á sára Àgọ́ náà àti ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀: yà pẹpẹ sí mímọ́ àti gbogbo ọ̀sọ́ rẹ̀, yóò sì jẹ́ mímọ́.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:1-10