Ékísódù 40:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta òróró sára pẹpẹ ẹbọ sísun àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, ya pẹpẹ náà sí mímọ́, yóò sì jẹ́ mímọ́ jùlọ.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:1-15