Ékísódù 40:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé pẹpẹ wúrà ti tùràrí sí iwájú àpótí ẹ̀rí, kí o sì fi aṣọ títa ẹnu ọ̀nà sí ara àgọ́ náà.

Ékísódù 40

Ékísódù 40:2-8