Ékísódù 33:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Mósè ṣe wọ inú àgọ́ náà, ọ̀wọ̀n àwọ̀ọsánmọ̀ yóò sọ̀kalẹ̀, yóò sì dúró sí ẹnu ọnà, nígbà tí Olúwa ń sọ̀rọ̀ pẹ̀lú Mósè.

Ékísódù 33

Ékísódù 33:5-12