Ékísódù 33:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbàkígbà tí àwọn ènìyàn bá rí i ti ọ̀wọ́n àwọ̀ọsánmọ̀ bá dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, gbogbo wọn yóò dìde wọn yóò sì sìn, olúkúlùkù ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ rẹ̀.

Ékísódù 33

Ékísódù 33:8-15