Ékísódù 32:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sọ fún Árónì pé, “Kí ni àwọn ènìyàn wọ̀nyí ṣe sí ọ, tí ìwọ ṣe mú wọn dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá yìí?”

Ékísódù 32

Ékísódù 32:18-28