Ékísódù 32:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé ẹgbọrọ màlúù tí wọ́n ṣe, ó sì fi iná jó wọn; ó sì lọ̀ wọ́n kúnná, ó dà á sínú omi, ó sì mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mu ún,

Ékísódù 32

Ékísódù 32:10-24