Ékísódù 27:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo irú iṣẹ́ tí ó wà kí ó ṣe, papọ̀ pẹ̀lú gbogbo èèkàn àgọ́ náà àti fún tí àgbàlá náà, kí ó jẹ́ idẹ.

Ékísódù 27

Ékísódù 27:9-21