Ékísódù 27:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àgbàlá náà yóò jẹ́ mítà mẹ́rìndìnláàdọ́ta (46 mítà) ni gíga àti mítà mẹ́talélógún (23 mítà) ní fífẹ̀, pẹ̀lú aṣọ títa ti ọ̀gbọ̀ olókùn mítà méjì ní gíga, àti pẹ̀lú ihò ìtẹ̀bọ̀ idẹ.

Ékísódù 27

Ékísódù 27:8-21