Ékísódù 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ yóò sì kọ pẹpẹ igi kaṣíà kan, ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta ní gígùn; Kí ìhà rẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin jẹ́ ìwọ̀n kan, ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní gíga àti ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún ní fífẹ̀.

Ékísódù 27

Ékísódù 27:1-6