Ékísódù 26:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe ìkọ́ wúrà fún aṣọ títa yìí, kí o sì bò ó pẹ̀lú òpó igi kasíà márùn ún pẹ̀lú wúrà. Kí o sì dà ihò ìtẹ̀bọ̀ fàdákà márùn ún fún wọn.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:35-37