Ékísódù 23:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ kò gbọdọ̀ gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀, nítorí àbẹ̀tẹ́lẹ̀ máa ń fọ àwọn tó ríran lójú, a sì yí ọ̀rọ̀ olódodo po.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:4-15