Ékísódù 23:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe lọ́wọ́ nínú ẹ̀sùn èké, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò gbọdọ̀ pa aláìṣẹ̀ tàbi olódodo ènìyàn, nítorí èmi kò ní dá ẹlẹ́bí láre.

Ékísódù 23

Ékísódù 23:2-15