Ékísódù 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú Jẹ́tírò dùn láti gbọ́ gbogbo ohun rere ti Olúwa ṣe fún Ísírẹ́lì, ẹni tí ó mú wọ́n jáde kúrò ni ilẹ̀ Éjíbítì.

Ékísódù 18

Ékísódù 18:5-19