Ékísódù 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sọ fún àna rẹ̀ nípa ohun gbogbo ti Olúwa tí se sí Fáráò àti àwọn ará Éjíbítì nítorí Ísírẹ́lì. Ó sọ nípa gbogbo ìṣòro tí wọn bá pàdé ní ọ̀nà wọn àti bí Olúwa ti gbà wọ́n là.

Ékísódù 18

Ékísódù 18:3-11