Ékísódù 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́tírò, àna Mósè, mú ọrẹ sísun àti ẹbọ wá fún Ọlọ́run. Árónì àti gbogbo àgbààgbà Ísírẹ́lì sì wá láti bá àna Mósè jẹun ní iwájú Ọlọ́run.

Ékísódù 18

Ékísódù 18:11-15