Ékísódù 18:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo mọ nísinsìnyìí pé Olúwa tóbi ju gbogbo àwọn òrìṣà lọ; nítorí ti ó gba àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìgbéraga àti ìkà àwọn ará Éjíbítì.”

Ékísódù 18

Ékísódù 18:2-17