Ékísódù 12:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pé ní ọjọ́ náà gan-an ni Olúwa mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì gẹ́gẹ́ bí ìpín ìpín wọn.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:45-51