Ékísódù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọjọ́ méje ni ẹ kò gbọ́dọ́ ni ìwúkàrà nínú ilé yín, ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ohun tí ó ni ìwúkàrà nínú ni a ó yọ kúrò ni àárin àwùjọ Ísírẹ́lì, ìbá à ṣe àlejò tàbí ẹni tí a bí ní ilẹ̀ náà.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:12-26