Ékísódù 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Búrẹ́dì ti kò ni ìwúkàrà ni ẹ̀yin yóò jẹ láti ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kọ̀kànlélógún osù àkọ́kọ́.

Ékísódù 12

Ékísódù 12:11-24