Éfésù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo ni fún Ọlọ́run àti Baba Jésù Kírísítì Olúwa wa, ẹni tí ó ti bùkún wa láti inú ọ̀run wá pẹ̀lú àwọn ìbùkún ẹ̀mí gbogbo nínú Kírísítì.

Éfésù 1

Éfésù 1:1-6