Éfésù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore ọ̀fẹ́ sí yín àti àlàáfíà, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wá àti Jésù Kírísítì Olúwa.

Éfésù 1

Éfésù 1:1-7