Deutarónómì 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lópin ogójì ọ̀sán àti òru wọ̀nyí, Olúwa fún mi ní sílétì òkúta méjì, sílétì òkúta májẹ̀mú náà.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:2-19