Deutarónómì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa fún mi ní òkúta méjì tí a fi ìka Ọlọ́run kọ. Lórí wọn ni a kọ àwọn òfin tí Ọlọ́run sọ fún un yín lórí òkè láàrin iná, ní ọjọ́ ìpéjọpọ̀ sí.

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:4-19