Deutarónómì 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ rántí Olúwa Ọlọ́run yín tí ó fún un yín lókun àti lè ní àwọn ọrọ̀ wọ̀nyí, tí ó sì fi mú májẹ̀mú rẹ̀ ṣẹ tí ó ti búra fún àwọn baba ńlá a yín bí ó ti rí lónìí.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:17-20