Deutarónómì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ lè rò nínú ara yín pé, “Agbára mi àti iṣẹ́ ọwọ́ mi ni ó mú ọ̀rọ̀ wọ̀nyí wá fún mi.”

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:7-20