Deutarónómì 5:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Súnmọ́ tòsí ibẹ̀ kí o sì gbọ́ gbogbo ohun tí Olúwa Ọlọ́run wa yóò sọ, nígbà náà sọ ohunkóhun tí Olúwa Ọlọ́run wa sọ fún ọ fún wa. A ó sì fetísílẹ̀, a ó sì gbọ́ran.”

Deutarónómì 5

Deutarónómì 5:25-29