Deutarónómì 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni nínú ẹlẹ́ran ara tí ó ti gbọ́ ohun Olúwa Ọlọ́run láti inú iná rí, bí àwa ti gbọ́ ọ, tí a sì wà láyé?

Deutarónómì 5

Deutarónómì 5:17-33