Deutarónómì 4:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gbogbo aginjù ní ìlà oòrùn Jọ́dánì títí dé òkun aginjù (òkun iyọ̀) ní ìṣàlẹ̀ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:39-49