Deutarónómì 4:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ wọ̀nyí bẹ̀rẹ̀ láti Áréórì ní etí odò Ánónì dé orí òkè Ṣíhónì (èyí ni Hámónì).

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:45-49