Nígbà náà ni Móṣè gun òkè Nébò láti pẹ̀tẹ́lẹ̀ Móábù sí orí Písigà tí ó dojú kọ Jẹ́ríkò. Níbẹ̀ ni Olúwa ti fi gbogbo ilẹ̀ hàn án láti Gílíádì dé Dánì,